Mo ti re’gbe mi,to sale la’kitan
Mo ti re’gbe mi,ti won da’wo po fun jeun lo’rita
Mo ti re’gbe ta’ye to ya ni weere ooo
Emi o se ni yin o o baba.
ika’moye egbe mi,ti wo o le da sohunkohun fun ra won
Emi to fun loju,fun lowo,fun ni gbogbo eya Ara, gbogbo re sa ni Mo wa dupe fun
Omo o ku Mo mi lowo,Oko o ku Mo mi Lori, Mo wa la’lafia oo
Emi o se ni yin o o baba
Mo ro aronjile
Lori aye mi o
Inu anu Baye mi de ok
aronjile no Mo ro
Mo rooooo arotunro oooo
lati igba ti o si ikankan to fi gbe mi de ibi Mo de
igba ta’ye sope oti tan,ti wo’olurun so ni gbangba pe o ku
awon Ilekun ta’ye so’pawon ti ti, iwo’olorun sope o sii
Emi ro arotunro,Mo ro aronjile ooo
ibi aanu Baye mi de oo
Aronjile ni mo to.
Gbogbo igba to Mo wo motor mo bole layo
ki see gbogbo eniyan to wo motor lo dele won pada oo
awa ta oun Jade Nile,ta oun bale la’lafia,eje a dupe
awa tolorun o gba kibi o kogun sile wa eje a gbega
aimoye egbe wa to be ni mortuary
aikamoye egbe wa to won to rale fun no grave yard oo
iwo tolorun dasi to yo ninu ewu lojojumo, oje gbega ooo
aanu ni Mo ri oo
aanu sa Lori ooo
Mo to arojinle
Lori aye mi ooo
ibi aanu Baye mi de oo
aro jinle no Mo roo
0 Comments