Ijoba A Re De lyrics – Sola Allyson Obaniyi


0

Ijoba Re de

Ase re bere

Ijoba Re de

Ase re bere

Agbara wa

O’ba sori mi

Ijoba Re de

Ase re bere

 

Ijoba Re de

Ase re bere

Agbara wa

O’ba sori mi

Ijoba Re de

Ase re bere

 

Ijoba Re de

Ase re bere

Agbara wa

O’ba sori mi

Ijoba Re De

Ase re bere

 

Ijoba Re de

Ase re bere

Agbara wa

O’ba sori mi

Ijoba Re de

Ase re bere

 

Ijoba Re de

Ase re bere

Agbara wa

O’ba sori mi

Ijoba Re de

Ase re bere

 

Ijoba Re de

Ase re bere

Agbara wa

O’ba sori mi

Ijoba Re de

Ase re bere

 

Ijoba Re de

Ase re bere

Agbara wa

O’ba sori mi

Okunkun ka, imole de

Iranwo de

Gbogbo ise n’kun Mi lowo

Okunkun ka o, imole de

Iranwo de

Gbogbo ise n’ kun Mi lowo

Ise mo wa se

Ise imole

Ma s’ase ye o

Ma rin a’rin to

Ma rin arin ‘ye

Agbara wa

O’ ba s’ori Mi

 

Okunkun ka, imole de

Iranwo de

Gbogbo ise n’kun Mi lowo

Okunkun ka o, imole de

Iranwo de

Gbogbo ise n’ kun Mi lowo

Ise mo wa se

Ise imole

Ma s’ase ye o

Ma rin a’rin to

Ma rin arin ‘ye

Agbara wa

O’ ba s’ori Mi

 

Mo f’ ebun sola

(Bee no Lori)

Mo f’ebun Mi fogo fun Oluwa t’o l’ebun mi

(Bee no Lori)

Ijoba Re De o

(Owo yida Lori iseda Mi)

Ase re lat’orun bere Bee noni

(Owo yida Lori iseda Mi)

Isodotun de bami n’irin ajo Mi

(Beeno Lori)

My remain shall not be few

Iranwo lat’origun mereerin agbaye temi ni

(Beeno Lori)

Awon toma gbemi………..

(Beeno Lori)

 

Ijoba Re De o

(Owo yida Lori iseda Mi)

Si ti aanu, Si ti Iranwo, Si ti ise ‘rere Beeno ni

(Owo yida Lori iseda Mi)

Iranwo ti Mi o’ riri Ma ri lona gbogbo Beeno ni

(Beeno Lori)

Aye Mi a bu’ola fun O Eni to ni Ebun Mi Beeno ni

(Beeno Lori)

Beeno Lori o pelu ase Baba Mi

(Owo yida Lori iseda Mi)

Moti di’omo Moti di’omo Moti di’omo

Apere Omo wa Lara Mi

(Owo yida Lori iseda Mi)

 

Agbara wa, O’ba s’ori Mi

Agbara wa, O’ba s’ori Mi


Like it? Share with your friends!

0

What's Your Reaction?

hate hate
0
hate
confused confused
0
confused
fail fail
0
fail
fun fun
0
fun
geeky geeky
0
geeky
love love
0
love
lol lol
0
lol
omg omg
0
omg
win win
0
win

0 Comments

Your email address will not be published. Required fields are marked *