Ki lo n ti ilekun, ilekun si
Ki lo n ti ilekun, ilekun si
Ki lo n ti ilekun, ilekun si
Ki lo n ti ilekun, ilekun si
E gb’ori yin soke, eyin enu onan
Ilekun si,
Oba ogo wole yi wa, ilekun si
E gb’ori yin soke, eyin enu onan
Ilekun si,
Oba ogo wole yi wa, ilekun si
Ki lo n ti ilekun, ilekun si (ki lo n ti ilekun)
Ki lo n ti ilekun, ilekun si (tani oke niwaju zerubabeli)
Ki lo n ti ilekun, ilekun si (Oba ogo wonu aye mi wa)
Ki lo n ti ilekun, ilekun si
E gb’ori yin soke, eyin enu onan
Ilekun si,
Oba ogo wole yi wa, ilekun si
E gb’ori yin soke, eyin enu onan
Ilekun si,
Oba ogo wole yi wa, ilekun si
Ki lo n fa okunkun, okunkun ka
Ki lo n fa okunkun, okunkun ka
Ki lo n fa okunkun, okunkun ka o
Ki lo n fa okunkun, okunkun ka
Eyin to wa ni’bi imole tan imole,
Imole yo, kilo n fa okunkun, Okunkun ka
Eyin to wa ni’bi imole tan imole,
Imole yo, kilo n fa okunkun, Okunkun ka o
Imole wole
Ki lo n fa igbekun, okun ja,
Ki lo n fa igbekun, okun ja,
Ki lo n fa igbekun, okun ja,
Ki lo n fa igbekun, okun ja,
Ati tu mi sile, mo gba ominira Okun ja,
Ki lo n fa igbekun, Okun ja,
A ti tu mi sile, mo gba ominira Okun ja
Ki lo n fa igbekun, Okun ja.
Ki lo n ti ilekun, ilekun si
Ki lo n ti ilekun, ilekun si
Ki lo n ti ilekun, ilekun si
Ki lo n ti ilekun, ilekun si
E gb’ori yin soke, eyin enu onan
Ilekun si,
Oba ogo wole yi wa, ilekun si
E gb’ori yin soke, eyin enu onan
Ilekun si,
Oba ogo wole yi wa, ilekun si
Oba ogo wole yi wa, (Oba ogo wole yi wa)
Imole wole, (Imole wole)
Okunkun ka (Okunkun ka)
Okun ja, (Okun ja)
Ki lo n ti ilekun, ilekun si
Ki lo n ti ilekun, ilekun si (Ilekun ayeraye agbe o soke)
Ki lo n ti ilekun, ilekun si
Ki lo n ti ilekun, ilekun si
E gb’ori yin soke, eyin enu onan
Ilekun si,
Oba ogo wole yi wa, ilekun si
E gb’ori yin soke, eyin enu onan
Ilekun si,
Oba ogo wole yi wa, ilekun si
Ki lo n ti ilekun, ilekun si
Ki lo n ti ilekun, ilekun si
E gb’ori yin soke, eyin enu onan
Ilekun si,
Oba ogo wole yi wa, ilekun si
E gb’ori yin soke, eyin enu onan
Ilekun si,
Oba ogo wole yi wa, ilekun si
Ki lo n fa okunkun, okunkun ka
Ki lo n fa okunkun, okunkun ka
Ki lo n fa okunkun, okunkun ka o
Ki lo n fa okunkun, okunkun ka
Eyin to wa ni’bi imole tan imole,
Imole yo, kilo n fa okunkun, Okunkun ka
Eyin to wa ni’bi imole tan imole,
Imole yo, kilo n fa okunkun, Okunkun ka o
Imole wole
Ki lo n fa igbekun, okun ja,
Ki lo n fa igbekun, okun ja,
Ki lo n fa igbekun, okun ja,
Ki lo n fa igbekun, okun ja,
Ati tu mi sile, mo gba ominira Okun ja,
Ki lo n fa igbekun, Okun ja,
A ti tu mi sile, mo gba ominira Okun ja
Ki lo n fa igbekun, Okun ja.
0 Comments