Chorus
Jesu
Imole ati Egan ati afara, sibi imole
Jesu
eni towaa, ife baba, feni tofe domo.
Jesu
Imole ati Egan ati afara, sibi imole
Jesu
eni towaa, ife baba, feni tofe domo.
J-e-s-u
eni naa eni naa to waa, ife baba, feni tofe domo.
Call: Jesu ooo
Resp: Jesu, Imole ati Egan ati afara, sibi imole
Cal: Alagbawi mi, Iwo ni Jesu
Resp: Jesu, eni towaa, ife baba, feni tofe domo.
Stanza 1
Imole, lati inu imole
o wa lati dawa pada sodo imole
okun to gbaye
ko je ko’ mo imole
won dite mon-on ife baba
O-lo-run didun eniyan, eniyan o didun
die iwon aguntan, sinu ile aanu
Ipase eniti mo gba igbala ati ilaja sodo baba, baye ti fifunni ko
imole sookun aye mi
ohun lo seto emi mi.
Chrs.
Jesu
Imole ati Egan ati afara, sibi imole
J-e-s-u
(Okan mi n saferi re nigbagbogbo, alasepe igbala mi) Jesu, eni towaa, ife baba, feni tofe domo.
Call: (Emi mi ke rara, mo pe J-e-su, alagbawi mi, Oku, Emi ye) Jesu, Imole ati Egan ati afara, sibi imole
J-e-s-u, eni towaa, ife baba, feni tofe domo.
Stanza 2
Eni wa imole
won a ri imole
bi won o mo imole, won a dite imole
Irora yan po gan
Eje ati Omi san gan-an
sibe o sakawe funwa pe, baba darijiwon won o mo ohun tonse
sa ti mohun a nse
baba darijiwon oo, nitori Imole,
ninu Irora, o tun fi iyonu wole itara
O ni Iya wo omo re, omo wo iya ree
O kigbe lohun rara, Olorun mi
eese ti o komi sile, eese to jumi’le, eese to jumi’nu
Ife po gan
oti kikan laye fun
awon ton wa imole
won fiya je imole
O ba pari, o pari
(Imole femi e sodo baba
O pari)
Nitori imole, nitori imole
aso ipele ya oo
Nitori imole, a le pe baba ni baba
Nitori imole
isa oku dofo
Eni bafe le waa domo.
Jesu, oga-ogo
Olori Ogun Orun
Omo alade alaafia
Alase orun
Aye e baba, baba laye o, baba layee
Aye mi tire nii
tan imole nipase mi
Ogo mi ko fogo fun o
Ola mi ko bu ola fun o
Chrs
J-e-s-u
Iwo ni imole
Iwo ni afara sibi ategun I-mo-le
J-e-s-u
Iwo ni eni naa towa
mo juba re
eni to so mi domo
mo juba re, eni to so mi domo, tire ni aye mi
itansan imole
latodore, mo juba re
Olugbala mi
Alasepe Igbala mi
eni to so mi domo
Mo juba re
eni to so mi domoo
0 Comments