Lebanon ko to jo Oloun iwo nika
Eranko igbe o to firubo
Niwa niwa :niwaju Oluwa
Niwaju Oluwa o ta won oke ti n yo bi ida
the Bible says lebanon is not sufficient to burn ,nor the beast thereof sufficient as sacrifice
Oluwa oluwawa orukore ti ni yin to
Nigbogbo aye ni gbogbo orun
Orukore ti ni yin to
Iba iba baba mi iba
okun ri osa jodani ri opada seyin
awon oke nla fo bi agbo,ato ke keke n fo bi odo agun tan
Ape ju ba kabiesi o
asiwaju ogun la lo,Akeyin ogun labo
Toluwani ile atekun re ,aye ati awon to tedo sinu re ,ofi idire sole lori okun ,o si gbe kale Lori ison omi,tani o goke oluwa lo,abi ta ni o duro ni bi mimo eh ,eni toni owo mimo, owo mimo ati Aya fun fun ,ti kosi gbe okan re soke si ason ,ti kosi bawon bura etan ,oun ni yi o ri ibunkun gba ,lowo olorun igbalawa
olorun awon omo ogun la o ma pe yin ,olorun awon omo ogun La o ma ki yin
Akoko o ,akoko ki
Olorun ti gbo aye n pe bo
balufo mogaji awon alagbara
Aji ri,Aji ki ,Aji sa
Olorun ajibo
Akoko da aye ,koseni ti o gbeyi re lo
ta n to ri o fin
eni kolu o ,wa run womu womu
0 Comments